Ọláḿbẹlóyè
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọláḿbẹlóyè
There's honour in chieftaincy. See: Ọláńbẹlóyè.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọlá-ń-bẹ-ní-oyè
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọlá - honour, wealth, success, nobility, notabilityń - continue to
bẹ - exist
ní - in
oyè - chieftaincy title, honor, prominence
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL