Ọlásẹ̀hìndèmí

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọlásẹ̀hìndèmí

Honour held firm in my absence.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-ṣe-ẹ̀hìn-dè-mí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - wealth, nobility, success, prestige, honour
ṣe - make, create (something good), do
ẹ̀hìn - back, behind, legacy
- for
- me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO



Irúurú

Ọlásẹ̀yìndémí