Ọláyọkùn
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọláyọkùn
Wealth grew.
Àwọn àlàyé mìíràn
Literally: success/wealth grew a fat belly. Affluence, prestige, human potential, largeness of heart, generosity of spirit, nobility, dignity, and grace etc. -- manifests/protrudes through (a potbelly).
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọlá-yọ-ikùn
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọlá - wealthyọ - show
ikùn - stomach
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OTHERS