Ọlábọ̀dé

Sísọ sítaÌtumọọ Ọlábọ̀dé

Wealth has come back.Àwọn àlàyé mìírànÌtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-bọ̀-déÌtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - wealth
bọ̀ - return
dé - arrive


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OTHERSÀwọn Ènìyàn Gbajúọ̀Ibi tí a ti lè kà síiIrúurú

Bọ̀dé, LábọdéẸ tún wo