Ọlánúsì

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọlánúsì

Increased prestige/honour/success/wealth...



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-ní-ùsì



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - wealth, nobility, success, prestige, honour
- have
ùsì - reputation, prominence, prestige


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO



Irúurú

Lánúsì