Ọnàṣowóbọ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọnàṣowóbọ̀

Artistry brought money/wealth back. Also: Ọnọ̀ṣowóbọ̀.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọnà-ṣe-owó-bọ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọnà - artistry
ṣe - make, do, perform
owó - money
bọ̀ - to return, to come


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL
OGUN



Irúurú

Ọnọ̀ṣowóbọ̀

Ọnáṣowó

Ọnọ̀ṣowó