Ọnànọ́lá

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọnànọ́lá

Artistry has nobility/success.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọnà-ní-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọnà - artistry
- have, own
ọlá - wealth, nobility, success


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
AKURE