Àbánikándá

Sísọ síta



Ìtumọọ Àbánikándá

The ant can only plot...



Àwọn àlàyé mìíràn

The full aphorism says "The ant can only plot, it can not eat into stone."



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

àbá-ni-ikán-ńdá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

àbá - plot, plan, strategy
ni - is
ikán - soldier ant
- continue to
dá - create, make