Àdùkẹ́

Sísọ sítaÌtumọọ Àdùkẹ́

One we eagerly compete to care for. A highly beloved one. People fight over the privilege to pamper her.Àwọn àlàyé mìíràn

A cognomen, oríkì.Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-dù-kẹ́Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

- someone (we)
dù - rush, gather around, compete for
kẹ́ - care for, cherish


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERALÀwọn Ènìyàn Gbajúọ̀

Àdùkẹ́ Gomez. Nigerian writer and poet.Ibi tí a ti lè kà síiIrúurúẸ tún wo