Àdúràtọ́lá
Sísọ síta
Ìtumọọ Àdúràtọ́lá
Prayer is as valuable as wealth/success/nobility.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
àdúrà-tó-ọlá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
àdúrà - prayerstó - enough for, suffice for
ọlá - wealth, success
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKO