Àgbéjìmí
Sísọ síta
Ìtumọọ Àgbéjìmí
Àgbé (Ọ̀sanyìn) entrusted me (with this child).
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
àgbé-jìn-mí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
àgbé - Ọ̀sanyìn, the Yoruba god of magic and herbal medicinejìn - entrust
mí - me
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI