Àníkẹ́

Sísọ sítaÌtumọọ Àníkẹ́

One you have/possess and cherish.Àwọn àlàyé mìíràn

It's a cognomen, oríkìÌtúpalẹ̀ Mọ́fímù

à-ní-kẹ́Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

- one who, we
ní - have, own
kẹ́ - pet, care for, take care of


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IBADAN
OTHERSÀwọn Ènìyàn Gbajúọ̀

Àníkẹ́ Agbájé-Williams (1936- ) Broadcaster: The first person, male or female to appear on Television in the whole of Africa. This was at WNTV-WNBS Ibadan on 31 October 1959.Ibi tí a ti lè kà síiIrúurúẸ tún wo