Aṣèyàn

Sísọ síta



Ìtumọọ Aṣèyàn

One with the qualities of a (great) human being.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-ṣe-èèyàn



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - someone
ṣe - make, do, perform
èèyàn - human being


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL