Abẹ̀rù

Sísọ síta



Ìtumọọ Abẹ̀rù

One who fears/revers (God/elders).



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-bẹ̀rù-àgbà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - the act of
bẹ̀rù - be scared of, be respectful of, have in awe
àgbà - elder


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Abẹ̀rùàgbà