Adétìmẹ́hìn

Sísọ sítaÌtumọọ Adétìmẹ́hìn

The crown hasn't become last.Àwọn àlàyé mìírànÌtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-è-tì-mú-ẹ̀hìnÌtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown
- has not
mú - take, pick, receive
ẹ̀hìn - last position (ẹ̀yìn)


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITIÀwọn Ènìyàn Gbajúọ̀Ibi tí a ti lè kà síiIrúurú

Adétìmẹ́yìnẸ tún wo