Adéṣùjọ
Sísọ síta
Ìtumọọ Adéṣùjọ
Royalty gathers (here).
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
adé-ṣù-jọ
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
adé - crown, royaltyṣù - gather
jọ - together, in collaboration
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ONDO
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Adéṣùjọ Adémúlẹ̀gún