Adébùsáyọ̀
Sísọ síta
Ìtumọọ Adébùsáyọ̀
The crown has added to our joy.
Àwọn àlàyé mìíràn
See: Olúbùsáyọ̀
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
adé-bù-sí-ayọ̀
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
adé - crown, royaltybù - scoop
sí - into
ayọ̀ - joy
Agbègbè
                        Ó pọ̀ ní:
                            
GENERAL                    
