Adégbòkìkí
Sísọ síta
Ìtumọọ Adégbòkìkí
The crown has received fame.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
adé-gba-òkìkí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
adé - crowngba - receive, take/take over, accept
òkìkí - notability, fame, success, herald
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL