Adégbóyèga
Sísọ síta
Ìtumọọ Adégbóyèga
The crown increased (our) honour.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
adé-gbé-oyè-ga
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
adé - crowngbé - carry
oyè - chieftaincy, honour
ga - tall
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
John Boyega
actor.