Adégbùsì

Sísọ síta



Ìtumọọ Adégbùsì

The crown has received fame.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-gba-ùsì



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown, royalty
gba - receive, take/take over, accept
ùsì - reputation, prominence, prestige


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO



Irúurú

Adéwùsì

Adéfùsì