Adékáyọ̀wá
Sísọ síta
Ìtumọọ Adékáyọ̀wá
Royalty brought joy in multitudes.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
adé-kó-ayọ̀-wá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
adé - crownkó - gather
ayọ̀ - joy
wá - come, arrive
kó...wá - bring
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ILESHA