Adérìndé

Sísọ síta



Ìtumọọ Adérìndé

The crown walks in.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-rìn-dé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown, royalty
rìn - walk
- to arrive


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ọlárìndé

Olúrìndé

Ayọ̀rìndé

Dérìndé