Adéyọ̀kúnnú
Sísọ síta
Ìtumọọ Adéyọ̀kúnnú
Royalty rejoices fully.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
adé-yọ̀-kún-inú
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
adé - crown, royaltyyọ̀ - rejoice
kún - in addition to, fulfillment, fill up
inú - stomach, inside, heart
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ILESHA
