Adéyẹmí

Sísọ síta



Ìtumọọ Adéyẹmí

1. The crown is befitting of me. 2. One who arrives to befit me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-dé-yẹ-mí, adé-yẹ-mí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who
- arrive
yẹ - to befit, to suit me, to be worthy of
- me
adé - crown


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀

  • 1. Làmídì Ọláyíwọlá Adéyẹmí III (the erstwhile Aláàfin Ọ̀yọ́) 2. Tómi Adéyẹmí: Nigerian author.



Irúurú

Adé

Déyẹmí

Yẹmí