Adépọ́nmilé

Sísọ sítaÌtumọọ Adépọ́nmilé

The crown has treated me honorably. Royalty treats me with respect.Àwọn àlàyé mìírànÌtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-pọ́n-mi-léÌtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown, royalty
pọ́n...lé - respect, hold in high regard
mi - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITIÀwọn Ènìyàn Gbajúọ̀Ibi tí a ti lè kà síiIrúurú

Pọ́nmilé, Pọ́nléẸ tún wo