Ajémíbọ̀wálé

Sísọ síta



Ìtumọọ Ajémíbọ̀wálé

Wealth is coming home.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ajé-mí-bọ̀-wá-ilé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ajé - the deity of business, entrepreneurship, and wealth
- ń (is)
bọ̀ - to return, to come
- seek, look for, come to
ilé - house, home


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IJEBU



Irúurú

Ajébọ̀

Ajébọ̀wálé

Ajéńbọ̀wálé