Ajétúnmọbí

Sísọ síta



Ìtumọọ Ajétúnmọbí

(The spirit of) entrepreneurship rebirthed (the child).



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ajé-tún-ọmọ-bí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ajé - the deity of business, entrepreneurship, and wealth
tún - again
ọmọ - child
bí - give birth to


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IBADAN



Irúurú

Ajétúmọbí