Ajíṣoge

Sísọ síta



Ìtumọọ Ajíṣoge

One who wakes up to make fashion.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-jí-ṣe-oge



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who
- wake up, arise
ṣe - make, create (something good)
oge - fashion, beauty


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ajíshoge

Ṣoge

Shoge