Akínfẹ̀léyè

Sísọ síta



Ìtumọọ Akínfẹ̀léyè

Bravery has blown onto honor/chieftaincy.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

akin-fẹ̀-lé-oyè



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

akin - valor, bravery, the brave one
fẹ̀ - to blow
- be added to, upon
oyè - honor, chieftaincy ttle


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO



Irúurú

Fẹ̀léyè