Akíngboyègbé

Sísọ síta



Ìtumọọ Akíngboyègbé

The warrior did not forget honor.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

akin-gbà...gbé-oyè



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

akin - valor, bravery, the brave one
gbà...gbé - forget
oyè - honor, chieftaincy ttle


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO



Irúurú

Gboyègbé