Akíntìmẹ́hìn
Sísọ síta
Ìtumọọ Akíntìmẹ́hìn
Bravery supported me.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
akin-tì-mọ́-ẹ̀yìn
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
akin - valor, bravery, the brave onetì - support
mọ́ - with, on
ẹ̀yìn - back, behind, future
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ONDO