Akíndáìní

Sísọ síta



Ìtumọọ Akíndáìní

This (child) belongs to valor solely.



Àwọn àlàyé mìíràn

See also: Dáminí



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

akin-dá...ní-èyí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

akin - valor, bravery, the warrior
dá...ní - alone, own
èyí - this (one)


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL