Akíngbọlá

Sísọ síta



Ìtumọọ Akíngbọlá

Valor receives honour.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

akin-gba-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

akin - valor/valiant, bravery/brave one
gba - receive, take/take over, accept
ọlá - prominence, prestige, wealth, honour, benefit


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OTHERS



Irúurú

Gbọlá