Akínwándé
Sísọ síta
Ìtumọọ Akínwándé
Valor sought me here. The brave one has come. The warrior has arrived in search of me.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
akin-wá-n-dé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
akin - valor, bravery, heroismwá - seek, look for
n - me (mi)
dé - arrive, return
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
1. Wándé Abímbọ́lá: Nigerian academic 2. Olúwọlé Akínwándé Ṣóyínká (Wole Soyinka): Nigerian Nobel Laureate.
