Anfọlájùwọ́n

Sísọ sítaÌtumọọ Anfọlájùwọ́n

We surpass them with wealth.Àwọn àlàyé mìírànÌtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-ń-fi-ọlá-jù-wọ́nÌtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - we
- continue to
fi - use
ọlá - wealth, success
jù - greater than, bigger than
wọ́n - them


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO
GENERALÀwọn Ènìyàn Gbajúọ̀Ibi tí a ti lè kà síiIrúurú

Fọlájùwọ́n, Jùwọ́n, FọlájùẸ tún wo