Ayọ̀wọnúọlá

Sísọ síta



Ìtumọọ Ayọ̀wọnúọlá

Joy has entered (our) honour.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ayọ̀-wọ-inú-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ayọ̀ - joy
wọ - enter
inú - stomach, inside, heart
ọlá - wealth, nobility, success, prestige, honour


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO



Irúurú

Wọnú

Wọnúọlá