Ayéremí

Sísọ síta



Ìtumọọ Ayéremí

I desire the world. The world attracts me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ayé-re-mí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ayé - earth, world, life
re - to attract
- me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OYO