Ayékẹ

Sísọ síta



Ìtumọọ Ayékẹ

One loved, cared for, by all.



Àwọn àlàyé mìíràn

User comment on a homographic equivalent: Ayẹ́kẹ́: "I just heard from a reliable source that it's actually Ayẹ́kẹ́ not Ayékẹ. I really have no idea what that means but I remember growing up, we used to call people with bowlegs Ayẹ́kẹ́. I'm assuming that was just his nickname." (Received on February 28, 2017)



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ayé-kẹ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ayé - the world, everyone
kẹ́ - cherish, care for


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKO



Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀

"There was a popular Sákárà legend from Ẹ̀pẹ́ named Nósírù Ayékẹ́. He was one of the early performers of Sákárà music and was the most popular artist in the whole of Ẹ̀pẹ́ until Lìgálí Múkáíbà." - Obethlalas



Ibi tí a ti lè kà síi



Irúurú



Ẹ tún wo