Bọ́látitó

Sísọ síta



Ìtumọọ Bọ́látitó

(Look) how big our prestige is.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

bí-ọlá-ti-tó



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

- like
ọlá - prestige, honour
ti - has
- as big as


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO