Bámidélé

Sísọ sítaÌtumọọ Bámidélé

Follow me home.Àwọn àlàyé mìírànÌtúpalẹ̀ Mọ́fímù

bá-mi-dé-iléÌtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

bá - help, together with
mi - me
dé - arrive at
ilé - home, house


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERALÀwọn Ènìyàn Gbajúọ̀Ibi tí a ti lè kà síiIrúurú

Bándélé, DeléẸ tún wo