Dọ̀pẹ̀mú
Sísọ síta
Ìtumọọ Dọ̀pẹ̀mú
One who holds the ọ̀pẹ̀ (divination chain).
Àwọn àlàyé mìíràn
See: Dòsùnmú.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
di-ọ̀pẹ̀-mú
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
dì...mú - hold ontoọ̀pẹ̀ - palm tree, divination chain (ọ̀pẹ̀lẹ̀)
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKO