Dọ́wọ̀lémi
Sísọ síta
Ìtumọọ Dọ́wọ̀lémi
(One which) bestows respect upon me, a shortening of the names Ifádọ́wọ̀lémi or Fádọ́wọ̀lémi.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
dá-ọ̀wọ̀-lé-mi
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
dá - to createọ̀wọ̀ - honour, respect
lé - be added to, upon
mi - me
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI