Dámiláre

Sísọ sítaÌtumọọ Dámiláre

Justify me.Àwọn àlàyé mìírànÌtúpalẹ̀ Mọ́fímù

dá-mi-láreÌtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

dá...láre - favour, justify, vindicate
mi - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERALÀwọn Ènìyàn Gbajúọ̀Ibi tí a ti lè kà síiIrúurú

DáreẸ tún wo