Díẹ̀kọ́ladé
Sísọ síta
Ìtumọọ Díẹ̀kọ́ladé
Royalty isn't inconsequential. The crown isn’t to be taken lightly.
Àwọn àlàyé mìíràn
Compare: Díẹ̀kádé, Díẹ̀kárá.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
díẹ̀-kọ́-ni-adé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
díẹ̀ - smallkọ́ - is not
ni - is
adé - crown, royalty
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL
ONDO