Fálébìtà
Sísọ síta
Ìtumọọ Fálébìtà
Ifa does not have wickedness.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ifá-à-ní-èbìtà
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ifá - Ifá divination, worship, priesthood, corpusà - one who; someone
ní - to have
èbìtà - wickedness, evil, trickery
Agbègbè
                        Ó pọ̀ ní:
                            
ONDO                            
EKITI                    
