Fálẹ́rù

Sísọ sítaÌtumọọ Fálẹ́rù

Ifá has awe.Àwọn àlàyé mìíràn

See: Adélẹ́rù.Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-ní-ẹ̀rùÌtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá corpus, priesthood, divination
ní - has
ẹ̀rù - fear, awe


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ILESHAÀwọn Ènìyàn Gbajúọ̀Ibi tí a ti lè kà síiIrúurú

Ifálẹ́rùẸ tún wo