Fáníkù

Sísọ síta



Ìtumọọ Fáníkù

Ifá is what's left.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-ni-ó-kù



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá divination, priesthood, corpus
ni - is
ó - he, she, it, they
- remain


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI