Fásùnlóyè

Sísọ síta



Ìtumọọ Fásùnlóyè

1. Ifá rests on honour 2. Ifá achieves honour even while at rest.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-sùn-lé-oyè, ifá-sùn-ní-oyè



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá divination, priesthood, corpus
sùn - sleep, rest, rely
- on
oyè - chieftaincy title, honor, prominence
- have


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO



Irúurú

IFásùnlóyè

Sùnlóyè