Firọpò

Sísọ sítaÌtumọọ Firọpò

Use for replacement.Àwọn àlàyé mìírànÌtúpalẹ̀ Mọ́fímù

fi-rọ́-ipòÌtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

fi - use (it)
rọ́ - exchange
ipò - status, position
rọ́pò - replace


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERALÀwọn Ènìyàn Gbajúọ̀

Firọ́pò Ewénlá, Nigerian thespian and academic.Ibi tí a ti lè kà síiIrúurú

Rọ́pòẸ tún wo