Gbìjà

Sísọ síta



Ìtumọọ Gbìjà

Support me in a fight. See: Adégbìjà, Olúgbìjà, etc.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

gbè-ìjà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

gbè - support, benefit, befit
ìjà - fight, struggle


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Adégbìjà

Olúgbìjà

Oyègbìjà

Ọ̀ṣúngbìjà

Ilégbìjà